ITAJA TABI IFERAN
Aworo iferan itaja
Oja mi koya, oja mi koya, oja mi koya, gbogbo awon ti a njo nta oja kanaa ni won nta jumi lo, ore wa osi kiye si ara re, bi eniti o nse alabaru baa dan ise yii wo, eru ni won yio fi pa, osi tun dara fun iferan pupo, sugbon emaa fi gba awon Iyawo mi o, mo kilo fun yin ooo, Asiri يا ودود ni todaju. hummm ona po bi a tun se ma nlo fun iferan toje wipe bi enia ko baa ti de shop ti o ti ntaja, won yio duro de ni kofi de.
…
..
Bi ase nlo fun inawo sise ki ale ri owo gba dada sakiti ewe die ti a gun yen ao fi ko ose dudu iwe ekan, ao fi omi hantu yen die po papo, ao sope ki omode kunrin kan ati omode binrin kan mun owo ototo dani ki won jina bi irin ese bata mefa si ibi ti ao ti we ose naa. Ti aba ti we tan awon omode mejeji yio waa fun waa lowo naa pada ao sope ESEUN ESEUN. Ao ma fi ipara re para titi ojo ti ao fi se inawo naa, aro bi ago mefa ni wiwe re.
Ewe a maa je oo