A o lo wa ewe sawerepepe oojo, omo aja, odidi atare nla meji, ewe ola, ewe aje oojo, ao fi ewe sawerepepe yen tele inu agbada ijogun, aowa gbe omo aje le lori omo aja ti koju ose kan lo nio, ao ko atare nla meji si legbe, aowa da ewe ola si, aowa da ewe aje tutu oojo lelori ti koni hon rara, dede agogo mejila osan lama jo ISEYI, leyin to ba jotan aolo, aowa ro sinu ado kan, ao ran aso asuwon funfun inu e la ma gbe ado yi si, ao gbe ko si ibikan ti koni kan le, ao gbe pamo fun ojo meje, leyin ojo meje, ao mafi schinapp lo laro kutu odaju.

One Thought on “OSHOLE TODAJU”

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *