OSHOLE OWO OLOWO DI TEMI

Ni aiye atijo, awon baba waa maa nsope bi aba se ise kan boya ise naa ododun tabi ososu ni lilo re, hummm aiye igba ti won maa ni yen, Laye igbanaa O isegun ko po to aiye isinyin, Beni Alfa kopo laye igba naa, ladugbo mi nikan mi o le ka iye Alfa, Woli, Onisegun to waa ladugbo mi, se iyen ni emi ma sope maa maa duro de odun kan ki nto we ose kan? Ko jo laye tawa yii rara.

Emaa binu bi mo se baa asiri yii je, walahi Asiri ni! Walahi Asiri ni!! Walahi asiri ni !!! Iru asiri bayi kose so sita, ema simi gbo oo, ko si part enia ni ibe o, sugbon oro ti o ko sinu Walahi asiri ni.

….

Odidi aso eegun togbayi, eja ojiji 16, oga oye 16, olongbo oye 16, ikun ojia ni opolopo gan, ewe alupaida pupo gan, eye okin kan, awa te aso egun naa sile awa mala awon ohun na mole lori re ti gbogbo won maku , awa fi aso egun naa we gbogbo won po pelu atare aja 201, awa gbe sinu agbada, awa da ewe sawerepepe lee lori ti yio bo ti koni han sita mo, awa jo papo awa igo nla rubutu tio le

OFORE : – oga, ologini gori aja oju tole otoko niti eyin iyami osoronga olokiki oru, ilu Loja yin o,efi oju si oja yin kielo owo nlanla lowo olowo wa fun mi ni kiakia, bi owo bakan ojiji ara aso giri ojiji a olowo wa fun mi ni kiakia lagbara eyin eleye aye , kiatose ise yi oni code kan ama pade code yii ninu iwe Wa Asiri Ewe ati Egbo ti o ma jade ni 26 Osu ti a waa yii

N8000

5 Thoughts on “OSHOLE OWO TEMI”

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *