IWE SE KI NFE ABI KI NMA FE? المادة
Oro lori iyawo nini ati oko fife.الموضع
..

Eri opolopo ninu waa ni ao mo pataki ti o waa ninu ki ama se ayewo okunrin tabi obinrin dada ki ato fe won sile, besini opolopo wa ni ko mo iwulo iyawo meji meta tabi merin ni fife sile. Gbogbo unkan pata ni Oba mi ti se eto re, oro Olohun oba kosi lo laise laye ati lorun. Nje gbogbo okunrin nifife? Nje gbogbo obinrin ni runrun? Opolopo okunrin loti kan iyalaya agbako besi be naa ni fun obinrin.
..
..
Iwo Alfa, Babalawo, woli ti a gbe ise waa yii dani, ti o si tun complain wipe iwo kori se ninu isee yii lofe iya kan le iyawo re ! Bi won bani tani oso be sope ewe nje ni. Ha! Olohun oba aleke ola ti pari awon ise kan si ara awon obinrin, ipo olukuluku lodo oko won yato sira won, iyawo mi ama ni ipo 35% 50% 70% 90% ati 100% nile oko.
..

A maa gbe apa kan won ga ju okan lo beni ose ri laye, iwo ti o nso pe ME AND MY HUSBAND ti unkan si nle lojojumo tenu ko kosi ogun re, ti o ba seso owo kole sise.. awon ipo iyawo ninu ile yato pupo lodo oko won, mio soro nipa ewa, tabi iwa, mo nso oro nipa arisiki ti oko yio ma ri lara won.
..
..
Awon iyawo kan waa, ti oko baa fe won ohun yio maa se oko naa ni wipe asiri ounje, owo school fees awon omo, owo aso wiwo yio ma bo sugbon kosi owo ile kiko, motor gungun koni si nibe. Sugbon iyawo mi wa tojepe ohun ko gbe bibo asiri kekere wa rara bi ki oko ma kole, ra motor lorisirisi. Irawo iyawo keji a maa ran ti akoko lowo.
..

Akiyesi, ki lode ti ojepe bi obinrin bawa nile oko ti kori bari omo bi, ti oko naa ba fe iyawo mi le iyawo naa bi iyawo tuntun ba loyun, ni Olohun a ba sina fun iyawo akoko. Walahi asiri ni.
..

..
Nidi eyii atife se agbekale iwe kan ti eo ma ba pade lori website wa ti yio ma toka si iru oko tabi iyawo ti ale fe, kini percentage number iyawo re lodo e, kini percentage oko re si o.
..
..
Ejeki ntu IRAWO LIBRA ATI GERMINI
Ategun ni awon mejeji yii nse, ategun ile keji ni Germini je beni ile keta ni libra je, bi awon mejeji ba pade ha! Oma rewa pupo gan nio. Eku oju lona lori alaye won lekun rere.
..
..
Talo sope ina ati omi kole fe ara won, nje gbogbo ina ni ina, nje gbogbo omi ni omi? Eku oju lona
..

Iwe naa yio jade laipe yii pelu N2000

10 Thoughts on “IWE ASIRI NLA”

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *