*ATUDE*
Hummmmm mofi asiri kekere yii sile ki afi ki arawa wipe aku aseku seminar oo, Olohun koni fi se asemo amin.
Gbogbo iwo ti o ti gbiyanju orisirisi Atude ti ko si ona abayo raaraa, odamiloju wipe opo ninu waa ni yio so wipe iro ni mo npa lori ise yii. ise yii ko naa waju N50
elo bami waa tomatoes to pon kan, iyo die, blade tuntun kan, kehinkehin ibile e bo ara sile ni ihoho, efi blade yen ge ori tomatoes yen tun geni idi, Akiyesi emun tomatoes yen dani ege si meta.
elo so ori ati idi yen danu, arin tomatoes yen ni ki efi si ori kehinkehin yen, efi ika meji bu iyo die si egbe kale fun bi iseju die, emaa se adua itusile, emun kehinkehin yen elo fi we pelu tomatoe to waa lori re, ema fi ose si raaraa. elo we bayen ni, ninu bathroom.
hu mmmmmmmm ti o baa baa unkan pade lara re, hummm ibiti kehinkehin baa kan lara re yio maa tutu gegebi wipe ice water ni enia nfi we ni.
massalam
AKIYESI
Emun tomatoes yen dani, e gesi meta, fun apere, ege ori re, ege idi re, e ju ori ati idi danu, ti arin ni ema lo, ti ko ba ye epemi
1. Anytime ni ele we iwe naa
2. iyo blade ati tomatoes ti e ge sile yen ko wulo mo
3. kehinkehin ti e fi we elo so danu ni
Se meeteeta ti a ba ge si yen lamaa ko si Ori kainkain leekan naa
ti arin
ESEUN ADUPE SIR
Thanks so much sir
Ise kin se itude o. Yio PA gbogbo Ogun arawa ni o. Neutralizing
Thank you oo
Thanks sir
Kinni a ma fi iyo yen se? Se a ma fi iyo yen na we mi?
Thank you baba ewe a ma he o