Ewe ewuro mejo, ewe ajeobale mejo, ewe lapa funfun mejo, sugar oni koro mejo a gunn papo a8 fi ose po, ao han ayah “Salam ala nuhu fil alamina 313, omi agbon lao fi fo ao fi po ose naa pelu lofinda danduala, ao ko sinu ike funfun ao maa bu we lararo

2 Thoughts on “Ose Eyonu”

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *