Ao wa agbon kan, ao jo omi re sinu cup kan, ao waa daa epo pupa si ao gbemun, ale maa se lekan losu tabi ekan lodun, bi won baa fun waa ni majele je koni sise lase edumare

4 Thoughts on “TI WON BA FUN WAA NI OGUN BURUKU JE”

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *