Epo obo die ao lo pelu ako okuta die, pelu eyo atare mesan fun okunrin meje fun obinrin, gbere mesan fun okunrin, meje fun obinrin larin ori odaju
Epo obo die ao lo pelu ako okuta die, pelu eyo atare mesan fun okunrin meje fun obinrin, gbere mesan fun okunrin, meje fun obinrin larin ori odaju
Ekasan sir, ejo kini molelo fun Kokoro inu eje to nda ago ara lamun bi orikerike ara, ara gbigbona, ori fifo, oyi oju ati inu, inu ara tita, oju susu, ara yunyun, ara kuku giri
emaa reti iwosan re ni ola
Baba wa president eku ise oluwa, olorun yio tubo maran yin lowo ,haa baba ona te tun ngba yi ti efinse omoaraye Loire yi ,olorun ko ni da oro tiyin na RU aaaaamiiiiiiina olorun yio tubo ma saanun yin ,eyin ati awon omo yin aaaamiiiiiiiiiiiiiiiiiiiiina
Amin