OGUN ASHINA TODAJU

Ewe lapa funfun, ewe lara funfun ati pupa, ewe ajeobale, ewe imi esu, ewe ewuro, ao gbo dada si omi ti o le to waa we, ao wa mu ose toba wuwa fiwe omi ti agbo yen

5 Thoughts on “Awure Asina”

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *