Egbo tude ao lo mon ota inu iroko  ao bu die sowo aote ni ifa ofun ao pe ohun esi aofi omin gbona loo bao se malo niyen

Ofore
Atakoro loruko ti anpe ofun
Ogidi loruko ti anpe edi
Alaforolo aja orun loruko ti anpe asasi ati epe
Idi igi ti aye tin tuni sile ni anpe ni tude
Lati onilo mogba itusile lowo oso aje emere ati alaburu aye gbogbo

Ota inu iroko ni iroko gbojule tiku kifipa ni rewerewe ki iku mapa emi lagbaja omo lagbaja ni rewerewe

7 Thoughts on “ATUDE TODAJU”

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *